SS3 Yoruba Past Questions and Answers- Mock (WASSCE). Get complete Yoruba past questions and answers to prepare for upcoming external examination.
Advertisements
You have been blocked from seeing ads.
';
endif;
?>
SS3 Yoruba Past Questions and Answers: Complete Questions
ÌPÍN A
ÀKÀYÉ
Ká àyo̩kà ìsàlè̩ yìí, kí o sì dáhùn ìbéèrè tí ó tè̩le e.
Advertisements
You have been blocked from seeing ads.
';
endif;
?>
Ìlú Ò̩là ni O̩láolú n gbé;ibè̩ ló sì bí gbogbo o̩mo̩ rè̩ sí. Gbogbo àwo̩n o̩mo̩ wò̩nyí ló kàwé dáadáa. Àwo̩n tí ó tí ké̩kò̩ó̩ jade ni Tìjání tí ó je̩ ako̩-níwájú-adájó̩. Bó̩lá ni adarí ilé is̩é̩ mádàámidófò kan ní Sò̩be̩. Lo̩ládé sì ní ò̩gá àgbà pátápátá ní ilé-ìwòsàn ìjo̩ba ní Àpà.
Dáramájà, akó̩s̩é̩-igi O̩láolú, ní gííwá ilé okoòwò káràkátà tí ara rè̩ ní Sohó. Rè̩mí tí í s̩e àbígbè̩yìn, nìkan ló kù ní ilé-è̩kó̩ gbogbo-nìs̩e ní Abraka. Dáramájà wòye pé ó ye̩ kí àwo̩n yé̩ bàbá àwo̩n sí fún is̩é̩ takuntakun tí ó s̩e lórí o̩mo̩. Wó̩n fe̩nu kò láti fi aye̩ye̩ o̩jó̩ ìbí yé̩ bàbá sí.
Ta ló dàgbà jù? (a) Bó̩lá (b) Rè̩mí (c) Dáramájà (d) Tìjání.
Ìlú ò̩là ni———– (a) O̩láolú bímo̩ sí (b) Dáramájà tí n s̩is̩é̩ (c) Rè̩mí tí n kàwé (d) ilé-ìwòsàn ìjo̩ba.
Àko̩lé tí ó bá àyo̩kà yìí mu jù ní—–(a) àwè̩je̩-mè̩mu (b) èrè tító̩ o̩mo̩ (c) o̩jó ìbí (d) ilú ò̩là.
Owó s̩e pàtàkì, ó s̩e kókó. Bí ó tilè̩ jé̩ pé owó kò fé̩ kí e̩niké̩ni dámò̩ràn Kankan lé̩yìn òun, síbè̩ a gbo̩dò̩ mò̩ pé ìr’ans̩é̩ ló jé̩. Kò yé̩ kí ó di ò̩gá fún e̩niké̩ni tí o̩ba òkè bá fi s̩e búrùjí fún. Láyé àtijó̩, bí e̩nikan bá s̩is̩é̩ tó lówó láàárín e̩bí, gbogbo e̩bí lápapò̩ ni yóò jànfààní rè̩. Ìmò̩ wo̩n nípa owó pé kò niran, kò jé̩ kí wó̩n di agbéraga. Bí àwo̩n bàbá wa tin i ìtara is̩é̩ ajé tó, wo̩n kì í sábà gbò̩nà àlùmò̩kó̩ró̩í wá owó. Lode òní, àwo̩n ènìyàn n digunjalè, wó̩n n s̩é̩s̩ó, wó̩n n gbó̩mo̩, wó̩n sì n gbé kokeènì láti lówó.
Àyo̩kà yìí fihàn pé owó jé̩——–(a) agbéraga (b) ò̩gá (c) ìráns̩é̩ (d) onítara.
Ò̩nà wo ló dára jù l’ati lówó? (a) os̩ó s̩ís̩é̩ (b) o̩mo̩ gbígbé (c) is̩é̩ s̩ís̩e (d) gbígbó̩ té̩bí.
Àkó̩lé tí ó bá àyo̩kà yìí mú jù ni —— (a) àwo̩n adigunjalè (b) owó níní (c) ànfààní olówó (d) gbígbé kokéènì.
ÀRÒKÒ̩/LÉ̩TÀ
Irúfé̩ àròko̩ won i is̩é̩ ni òògùn ìs̩é̩ je̩ mó̩ jù? (a) aje̩mó̩-ìs̩ípayá (b) ìsò̩rò̩ngbèsì (c) as̩àpèjúwe (d) asò̩tàn.
Èwo ní ó jè̩ mó̩ àròko̩ aje̩mó̩-ìs̩ípayá jù? (a) is̩é̩ déré̩bà dára ju is̩é̩ káfíntà lo̩ (b) ilé ìgbè̩bí àdúgbò mí (c) ìwà o̩mo̩lúàbí (d) eré orí ìtàgé kan ti mow ò.
Èwo ni orí-ò̩rò̩ tí ó je̩ mó̩ àròko̩ asò̩tàn jù? (a) abé̩ré àje̩sára (b) o̩wó̩ o̩mo̩dé ò tó pe̩pe̩ (c) ìrìn àjò kan tí mo lo̩ lójú omi (d) dídé̩kun ìwà ìbàjé̩ ní àwo̩n ilé ìwé wa.
Lé̩tà gbè̩fè̩ ni lé̩tà sí——- (a) ìyàwó àfé̩só̩nà (b) ilé is̩é̩ àdáni (c) Gómínà ìpínlè̩ (d) àjo̩ èrò ìrìnnà.
My journey to the beach was successful (a) mo paŕI ìrìn àjò mi śI et́ikun (b) ìrìn àjò mi si et́ikun yo̩ŕI śI rere (c)ìrìn àjò mi ńI et́ikun yo̩ŕI śI rere (d) mo paŕI ìrìn àjò mi śI et́ikun.
Half a loaf is better than none. (a) ààbò̩ b́uŕe̩dì sàn ju òfo lo̩ (b) ́o d́ara b́uŕe̩dì wà ĺáabò̩ jù odindi ĺo̩ (c) ààbò̩ ýa ju aĺaìŕI ŕaŕa (d) ohun t́o so̩nù ni à n ẃa kiri.
The labour union appealed to workers to be patient. (a) àjo̩ òs̩ìś̩e̩ pàro̩wà f́un àwo̩n òs̩ìś̩e̩ ĺati ńI sù́urù (b) ajò̩ òsìs̩è̩ f́e̩ ḱI àwo̩n òs̩ìś̩e̩ śo̩ra gidigidi (c) àjo̩ òs̩ìś̩e̩ kò faramo̩ àìńI sù́urù àwo̩n òs̩ìś̩e̩ (d) àjo̩ òs̩ìś̩e̩ be̩ àwo̩n òs̩ìś̩e̩ ĺati gba ḱaḿu.
It is nice to see you again. (a) ́o d́ara t́I mo ŕI o̩ (b) ́o d́ara t́I a t́un ŕI ara wa (c) o d́ara ḱI a ŕira (d) ́o dara ḱI a lè ḿaa ŕira wa.
ÌṔIN B-ĹIT́IŔES̩Ò̩
Ànḱasiìfù ýin ti s̩ub́u. ò̩rò̩ t́I ́o ye̩ ḱI a fi d́ipò ‘s̩ub́u’ ni ——-(a)pò́oŕa (b) dò̩t́I (c) wo̩ĺe (d) j́ab́o̩.
Afèrìgìpè (ii) afàfàsèfètè pè (iii) àìkùnyùn (iv) àkùnyùn.
(b) fi m’eje ńińu àwo̩n ḱo̩nśonàntì t́I o ko̩ ni 3(a) hàn ńinu ò̩rò̩ ḿee ò̩tò̩ò̩tò̩( fi àmì ohùn śI ori àwo̩n àpe̩e̩re̩ re̩).
GRÁMÀ
Dáhùn ibèèrè kan s̩os̩o nihin-in
(a) Ko̩ àpe̩e̩re̩ kò̩ò̩kan fún àwo̩n è̩yà ò̩rò̩ is̩e wò̩nyi ki ó si lò ó ninú gbólóhùn: (1)as̩èbéèrè (ii) alápèpadà (iii) as̩èróyin (iv) àsinpò̩ (v)as̩òkùnfà.
(b) Lo àwo̩n ò̩rò̩ wò̩nyi gé̩gé̩ bi olùwà tàbi àbò̩ ninú gbólóhùn: (i) ikú (ii) itura (iii) àdúrà (iv) o̩gbó̩n (v)àánú.
Ye̩ `awo̩n gbólóhùn wò̩nyi wò ki o si dáhùn àwo̩n ibéèrè ti ó tè̩lé wo̩n: (i)O lo̩ (ii) Gbogbo wa ni a ri I (iii) Wó̩n ti s̩etán (iv) Tis̩à máa n gba iwé yin (v) N ó s̩e bi o ti wi
(a) s̩e àpèjúwe àwo̩n ò̩rò̩ ti a fàlà si nidii.
(b) So̩ ò̩kò̩ò̩kan gbólóhùn náà di gbólóhùn àyisódi.
IPiN B:LiTiRÉS̩Ò̩:
D́́ahùn ìb́eèrè ḿe̩ji ṕeŕe ńińu ìṕin yì́i.
Itàn àròs̩o̩:àkójo̩pò̩ àló̩-ìjàpá.
Ninú `aló̩”ijàpá àti ìyá è̩lé̩pà” sàlàyé ohun ti ó fà á ti ò̩sanyin e̩lé̩sè̩ kan mú ijàpá lo̩ si ilé O̩ba.
Àwo̩n oriki orilè̩ mé̩tàdinlógbò̩n.
Ninú oriki iran Àágberi” sàlàyé bi Àágberi s̩e di o̩mo̩ e̩kùn ayé.
ERÉ- ONiSE:ègè dídá
Ki ni pàtàki tàbi iwúlò ègè dídá?
LiTiRÉS̩Ò̩ ÀPiLÈ̩KO̩
Dáhùn ibèèrè kan s̩os̩o nihin-in:
Mó̩remí àjàsorò.
Sàlàyé lóri onirúurú às̩à ilè̩ Yorùbá ti ó je̩yo̩ ninú rè̩.
Ewi: ò̩rò̩ e̩nu akéwì:
Sàlàyé lé̩kùnré̩ré̩ kókó ti akéwi mé̩nubà lóri pè̩gànpè̩gàn.
Eré-onitàn : nítorí owó
È̩kó̩ wo gan-an ni ònkò̩wé yii fi itàn inú iwé rè̩ kó̩?
IPiN D: ÀS̩À
Sò̩rò̩ lóri ò̩nà ti à n gbà yá owó ni ilè̩ Yorùbá.
Hi guys!
Meet Deborah Hiny, a passionate blogger and biochemist with a flair for all things science and education. With a love for learning and exploring, she's always on the lookout for the latest educational updates and trends. When she's not blogging, you can find her planning her next adventure or traveling to new destinations. As the founder of EduPunch, Deborah shares her enthusiasm for education and science with readers, inspiring and informing them along the way.